ADVERTISEMENT
Ondo State Government has introduced the compulsory recitation of the Oodua Anthem in all schools in the State.
ODUA ANTHEM
Ise wa fun ile wa
Fun ile ibi wa
Kagbega kagbega kagbega faye ri.
Igbagbo wa nipe
Bati beru la bomo
Kasise kasise kasise kajola
Isokan atominira
Ni keje kama lepa
Tesiwaju fopo ire
Atohun to dara
Omo Odua dide
Bosi ipo eto re
Iwo ni imole
Gbogbo adulawo.